KidsOut World Stories

Alantakun Ati Awon Ore Re Meji Abimbola Alao    
Previous page
Next page

Alantakun Ati Awon Ore Re Meji

A free resource from

Begin reading

This story is available in:

 

 

 

 

Alantakun Ati Awon Ore Re Meji

 

 

 

 

 

Alantakun ti e ri yen, o ni ore meji kan
Okan labule otun, ekeji lapa osi
Ore ekini wole dee
O ni mo fe sase kan fawon ilu
Mo si fe ki o je kan ninu won
Inu awe ti dun lopolopo o tun ferin si
O ni kini kan ni o je ka se
Je n so’kùn kan mo badi
Ki e mu ori okun rele, nigbati e ba sounje tan
Ki e f’okun yen fa mi mora
Werewere ni n o yara mo
Pe ẹ ti toju ounje tan
E ma a reti mi
Ko pe ko jina lo titi, lọ̀rẹ̃ keji wole de
O ni mo fe s’ase kan
Oni ni mo f’ase ọ̀hun si
Mo si fe ko je kan ninu won
Inu awe ti dun lopolopo, o tun ferin si.
O ni kini kan ni e je ka se
E je nso’kun kan mo ‘badi
Ki e mu ori okun yen re’le
Nigbati e ba s’ounje tan
Ki e f’okun yen fa mi mora
Werewere ni n o ti da o mo
Pe e ti toju ounje tan
E ma a reti mi
Ko pe ko jina lọ titi, ore ekini sounje tan
Ko pe ko jina lọ titi, ore ekeji sounje tan
Tihin nfaa, tọ̀hun nfaa nisẹ́ ba di sise
Lori ese kan aye, ese kan ọ̀run
Ẹ ò ráye lóde e.

Enjoyed this story?
Find out more here